KA DO UDOẸYE OLELE KRAIST
Wo Nemi Mu Lu Ọyọ ti O wi Ẹbi We
Jihova fẹ di ẹbi nẹ arayinyọn. (Sam 127:3-5; Ẹkli 9:9; 11:9) Dẹreke dẹ, ọyọ ti ẹnẹ nẹ nemi tafu ẹnẹ ẹwọ teri kpokpo ẹye we biri iṣẹwọṣe ira ẹbi ẹnẹ. Nikọ unọkọkan ni ẹbi nemi ṣe gba mu lu ọyọ we?
Ọkọ ka gba oye gba biri aya ro do. (1Pit 3:7) O ka biri o lo ira ni ara. Ee ka gin di o ṣe urun ti ẹmi ro ee ka, kẹnrẹn urun ti aya ro ka ṣe gbẹ wun biri ẹbi we ka kọn wun eju. (Kol 3:15) O ka lẹghẹ aya ro man gin won fẹ ọfọ ro, kẹnrẹn o ka yirii.—Owe 31:28, 31.
Ebirẹn aya-ọlọkọ ka fẹ ewe gba mu utiẹyin gbẹ ọkọ ro. (Owe 31:12) O ka gba ara re alẹ gbẹ ẹ, kẹnrẹn gba mu utiẹyin gbẹ ero ti ọkọ ro da. (Kol 3:18) O ka gba owun akpẹ gba biri o fọ biri gba fọ urun ti o san ni ubara ro.—Owe 31:26.
Ọsa biri ore ka biri ọtọn aghan lo ira ni ara. (Diut 6:6, 7) Aghan ka gin gbẹ ọtọn aghan gin aghan fẹ ọfọ aghan. (Mat 3:17) Aghan ka lo wuwu biri oye gba kpanran eju sin ọma ghaan.—Ẹfi 6:4.
Di aghan ọma ka mu ọghọ gbẹ ọsa biri ore gba da ẹsi aghan ni. (Owe 23:22) Aghan ka gin urun ti o wi ẹmi aghan biri biri o te ṣe aghan ni ara gbẹ ọsa biri ore aghan. Aghan ka gba ẹkọ ni ẹwọ ọsa biri ore biri gba mu ọghọ gbẹ aghan.—Owe 19:20.
GHO VIDIO IṢEMUGHAN WE NẸ ỌYỌ NI ẸBI RẸ, KURO DI AGHAN GBA IWANRAN NI UBIRỌ TI O LELE:
• Nikọ wun unọkọkan ṣe di aghan gba mu lu ọyọ ti o wi ẹbi we?