November 25–December 1
SAM 109-112
Ẹrin 14 Biri Iṣẹ | Ọfọ Ọṣọgua ti Ọlaga Wa Fọ (uṣẹju 1)
1. Mu Utiẹyin gbẹ Ọlaja Ẹnẹ, Jisọs!
(uṣẹju 10)
Ira ti Jisọs gba yidẹ re ọrọn, o ka ṣikalẹ ni ẹwọtọn Jihova (Sam 110:1; w06-E 9/1 13 ¶6)
Ni ọdọn 1914, Jisọs ka winọrọn jẹ ni origho aghan ọghanran ro (Sam 110:2; w00-E 4/1 18 ¶3)
Ẹnẹ nemi gba ayẹ-inọ ẹnẹ mu ara ṣi, di ẹnẹ gba nemi mu utiẹyin gbẹ sisin Jisọs (Sam 110:3; lff ẹkọ 55 ẹkori 1)
BI ARA RẸ RỌ, ‘Nikọ mo nemi da ero gin mo wa ṣe ti o wa mughan gin mo winọrọn mu utiẹyin gbẹ Oye we?’
2. Uwa Ẹmi
(uṣẹju 10)
-
Sam 110:4—Wewe nina ti o wi ẹsẹn Baibol we. (it-1-E 524 ¶2)
-
Uwa ẹmi bokọ wo ri ni Baibol ti a rọ ni ọjijala eyiwe ti wo wa fẹ fọ ni ubara ro?
3. Rirọ Baibol Usoro
(uṣẹju 4) Sam 109:1-26 (th ẹkọ 2)
4. Mimu Arun ni Ọfọ
(uṣẹju 2) KURI ẸGẸRIFO RA WỌ ẸGẸRIFO. Lo trakt ọkan gba ṣẹ fifọ ni ara. (lmd ẹkọ 4 ẹkori 3)
5. Wiwewe Urun ti Wo Kpe Ni Ọrọnfọ
(uṣẹju 5) Iṣemughan. lff ẹkọ 45 ọfọ ọṣọgua, biri ẹkori 1-2—Origho Ọfọ: Nikọ Re Ṣe ti Aghan Oṣẹri Jihova Ee Gba Ja Ogun Biri Gba Nẹ Ẹwọ ni Pọlitis? (lmd ẹkọ 4 ẹkori 4)
6. Sisọ Irẹye Da Olele Kraist
Ẹrin 72
7. Bokọ Ẹnẹ Te Nemi Gba Ẹmi Ẹnẹ Dede Mu Utiẹyin gbẹ Oye We?
(uṣẹju 15) Ọfọ ti a fọ ni ara.
Ewe ọkan ti Jihova gba mughan gin owun re ṣe ọkpaṣẹ ni ẹye biri ọrọn dede ka ṣe Oye ro ti won mu do. (Dan 2:44, 45) Teri ẹrẹn, ẹnẹ ma ṣe urun dede ti ẹmi ẹnẹ ka gba mu utiẹyin gbẹ Oye Oriṣẹ, ẹnẹ winọrọn mughan gin ẹnẹ kpe e ni ọrọnfọ gin aṣẹ-kpikpa Jihova re san ju fẹnẹfẹnẹ.
Lu VIDIO we Gba Ara Re Alẹ Gba Lele “Ọtọn Ọlaja Aratutun.” Kuro bi aghan ti o wi iṣikalẹ rọ:
-
Bokọ ẹnẹ te gba ẹmi ẹnẹ dede mu utiẹyin gbẹ Oye Oriṣẹ?
Ni ewe ghaan ti ẹnẹ kele nemi mu utiẹyin gbẹ Oye Oriṣẹ, ya ẹsẹn Baibol ti o biri ukalẹ ọkan-ọkan jọ.
-
Mimu Oye we ṣi ọgua ni ẹye ẹnẹ.
-
Lilele ẹsi ọgbarara ti o yẹle gbẹ aghan ti o wi abẹ Oye we.
-
Gbigba oruru gin gbẹ irẹye mirẹn ni ubara Oye we.
-
Mimu ọghọ gbẹ udẹrini irẹye. Dẹ o ma gbesin ti Oriṣẹ, ti Oriṣẹ ẹnẹ wa ṣe.
8. Ẹkọ Baibol ti Ujọ Dede
(uṣẹju 30) bt origho 18 ¶16-24