Wo Man Ṣi?
Nikọ re lẹghẹ aghan bọbọ ti ee ṣe ira Isrẹl gba wi ẹbu aghan ọja-ogun Ọlaja Defid?
Aghan bọbọ ti ee ṣe ira Isrẹl ti o wi ẹbu aghan ọja-ogun Defid ka ṣe ẹkẹnrẹn ṣiṣi, Selẹk ira Amọn, Uraya ira Iti, biri Itama ira Moab. a (1 Kro. 11:39, 41, 46) “Aghan Cherethite, Pelethites, biri aghan Gittite” wi ẹbu aghan ọja-ogun Defid kẹnrẹn. (2 Sam. 15:18) Aghan Gittite ka ṣe ira Filiṣia, kẹnrẹn a gba a gin aghan Cherethite biri Pelethite biri ira Filiṣia, omere rẹẹn.— Ẹsi. 25:16; Joṣ. 13:2, 3; 1 Sam. 6:17, 18.
Nikọ Defid teri ro gba forijẹ di irẹye ti ee ṣe ọma Isrẹl wi ẹbu ọja-ogun ro? O da wun eju gin aghan wa tama wun, kitikiti gba tama Jihova. Ni ewe, ni ubara aghan Cherethite biri aghan Pelethite, The New Interpreter’s Dictionary of the Bible gin: “Aghan tama Defid ni ira ti ẹkpikpomẹ ro gba jọlọ ni, ti won gba wi oye.” Bokọ aghan te ṣe mu wuwu are-yẹ aghan ghan? Ira ti “ẹkẹnrẹn Isrẹl” gba ju Ọlaja Defid ṣi gba lele “ọnẹ are-wọ urun ti a kpe wun Ṣẹba,” aghan Cherethite biri Pelethite ka biri Defid winọrọn, gba tin wun ẹyin gba gba ọgua ọtẹ Ṣẹba. (2 Sam. 20:1, 2, 7) Ni ira mirẹn, Adonija ọtọn Ọlaja Defid ka fẹ gba nini gba ara ro ṣe Ọlaja ni ubo Solomọn. Dẹreke, aghan Cherethite biri aghan Pelethite kpe tama Defid gba tin wun ẹyin gba mu Solomọn, ọnẹ ti Jihova fẹsẹn di o ṣe ọlaja ni ubo Defid, mu jẹ.—1 Ọla. 1:24-27, 38, 39.
Oniye mirẹn ti o jọlọ tama Defid ka ṣe Itai ti o ṣe Gittite. Itai biri aghan ọja-ogun ro ọru mẹẹfa ka soro tin Ọlaja Defid ni ira ti ọtọn ro Absalọm gba ṣe ọtẹ siin biri gba fẹ ṣe di aghan ẹkẹnrẹn Isrẹl dede gba wun ṣe Ọlaja okpinju Defid. Defid ka gin gbẹ Itai gin ee yẹle gba ja gbẹ wun teri ee ṣe ira Isrẹl. Dẹ Itai ka gin: “Afọmaasin, mo gba ọrukọ ỌLUWA gba na uwọ gin mo wa biri uwọ re ubo-kubo ti wo man re dede, o man wuu di o nẹ uku.”—2 Sam. 15:6, 18-21.
O wu gin aghan Cherethite, Pelethites, biri aghan Gittite ṣe ẹjoji, aghan mu ọghọ ti o jẹn gbẹ Jihova gin owun re ṣe Oriṣẹ ọrọnfọ, kẹnrẹn aghan mu ọghọ gbẹ Defid, ọnẹ ti Jihova gba ekpo nẹ gbẹ. Biri o te kọn Defid eju gin ẹkẹnrẹn egbe ighaan ti o nẹ wuwu are-yẹ gbẹ wun biri owun winọrọn!
a Ẹsi Oriṣẹ ti a ya ni iwe Diutaronomi 23:3-6 gin di ira Amọn biri ira Moab maa wọ ugbarajọ aghan ira Isrẹl. Dẹ, o ṣiṣi gin ẹsi eyiwe winọrọn fọ ni ubara ṣiṣe ọkan ni ewe ẹsi ni aja we. Ee gin di ẹjoji ghaan maa biri aghan lo, wẹrẹ gba kani ẹgbelemeeji ira Oriṣẹ, kitikiti ni aghan ma forijẹ usẹn ọrọnfọ. Ṣọn Insight on the Scriptures, Volume 1, p. 95.