‘Kí Ọ̀rọ̀ Wọ̀nyí Wà ní Ọkàn Rẹ’
‘Kí Ọ̀rọ̀ Wọ̀nyí Wà Ní Ọkàn Rẹ’
Kí lohun tí àwọn ọmọ nílò jù látọ̀dọ̀ àwọn òbí wọn? Wo ohun tí bàbá kan ṣe láti tún ìdílé rẹ̀ tò.
Ìjọsìn Ìdílé: Àwọn Ìṣòro àti Ayọ̀ Ibẹ̀
Tí ìdílé bá ń wáyè láti jọ sọ̀rọ̀ nípa Jèhófà lọ́sọ̀ọ̀sẹ̀, wọ́n á túbọ̀ sún mọ́ ọn, wọ́n á sì tún sún mọ́ ara wọn.
O Tún Lè Wo
ÌDÍLÉ RẸ LÈ JẸ́ ALÁYỌ̀
Ẹ Jọ Máa Sin Jèhófà Nínú Ìdílé Yín
Báwo lo ṣe lè túbọ̀ gbádùn ìjọsìn ìdílé rẹ?