Dáníẹ́lì Nígbàgbọ́ Jálẹ̀ Ìgbésí Ayé Rẹ̀

Nǹkan ò rọrùn fún Dáníẹ́lì torí pé wọ́n mú un kúrò lọ́dọ̀ àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ̀. Síbẹ̀ kò fi Jèhófà sílẹ̀, ó sì ṣe gbogbo ohun tó lè ṣe kí ìgbàgbọ́ ẹ̀ lè lágbára.

Dáníẹ́lì Nígbàgbọ́ Jálẹ̀ Ìgbésí Ayé Rẹ̀—Apá Kìíní

Wọ́n mú Dáníẹ́lì kúrò lọ́dọ̀ ìdílé rẹ̀, wọ́n sì pa ìlú rẹ̀ run, ṣé ó ṣì máa jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀?

Dáníẹ́lì Nígbàgbọ́ Jálẹ̀ Ìgbésí Ayé Rẹ̀—Apá Kejì

Ọba tuntun tó lágbára gorí oyè. Àwọn ọ̀tá míì tún bẹ̀rẹ̀ sí í gbógun ti Dáníẹ́lì. Àwọn alátakò yìí dán ìgbàgbọ́ Dáníẹ́lì wò ju ti tẹ́lẹ̀ lọ.