Ṣé Ọlọ́run Wà Lóòótọ́?
Wo àwọn ẹ̀rí tó jẹ́ ká gbà pé Ọlọ́run wà lóòótọ́.
Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́
Fídíò Tó Dá Lórí Bíbélì—Ẹ̀kọ́ PàtàkìO Tún Lè Wo
OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ
Ǹjẹ́ Ọlọ́run Wà?
Bíbélì fún wa ní ẹ̀rí márùn-ún tó jẹ́ ká mọ̀ pé lóòótọ́ ni Ọlọ́run wà.
ÀWỌN Ẹ̀KỌ́ PÀTÀKÌ INÚ BÍBÉLÌ
Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Gbà Pé Ká Máa Jìyà?
Ọ̀pọ̀ èèyàn ló máa ń béèrè pé kí ló fà á tí ìkórìíra àti ìyà fi pọ̀ láyé. Bíbélì dáhùn ìbéèrè yìí lọ́nà tó tẹ́ni lọ́rùn tó sì tuni nínú.
ÀLÀYÉ ÀWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ
Àlàyé Jẹ́nẹ́sísì 1:1—“Ní Ìbẹ̀rẹ̀, Ọlọ́run Dá Ọ̀run àti Ayé”
Òtítọ́ pàtàkì méjì wo ni gbólóhùn tó bẹ̀rẹ̀ ẹsẹ Bíbélì yìí sọ?
OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ
Báwo Lo Ṣe Lè Mọ Ọlọ́run?
Ohun méje tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó o lè di ọ̀rẹ́ Ọlọ́run.
ÀWỌN Ẹ̀KỌ́ PÀTÀKÌ INÚ BÍBÉLÌ
Ṣé Ọlọ́run ní Orúkọ?
Ọlọ́run ní ọ̀pọ̀ orúkọ oyè, lára rẹ̀ ni Olódùmarè, Ẹlẹ́dàá, àti Olúwa. Fídíò yìí sọ orúkọ Ọlọ́run gangan èyí tó fara hàn ní ibi tó lé ni ẹgbẹ̀rún méje [7,000] nínú Bíbélì.
ÀWỌN Ẹ̀KỌ́ PÀTÀKÌ INÚ BÍBÉLÌ