Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

“Jèhófà . . . Ìwọ Ni Mo Gbẹ́kẹ̀ Lé”

Wo bí Hesekáyà ṣe borí ìṣòro lọ́tùn-lósì kó lè ṣe ìpinnu tó dá lórí ìgbàgbọ́ àti ìdúróṣinṣin, tó sì tipa bẹ́ẹ̀ fi àpẹẹrẹ rere lélẹ̀ fáwọn ọmọ ìlú rẹ̀ àwọn gbogbo àwọn tó ń sin Jèhófà lónìí.

O Tún Lè Wo

ÌWÉ ÌTÀN BÍBÉLÌ

Ọlọ́run Ran Hesekáyà Ọba Lọ́wọ́

Ní òrú ọjọ́ kan, áńgẹ́lì kan pa 185,000 ọmọ ogun Ásíríà.