Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ọgọ́rùn-ún Ọdún Ti Kọjá, Ìjọba Ọlọ́rùn Ṣì Ń Ṣàkóso

Kí ni Ìjọba Ọlọ́run ti gbé ṣe láti ọgọ́rùn-ún ọdún tó ti ń ṣàkóso?

 

O Tún Lè Wo

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Sinimá Tó Dá Lórí Ìṣẹ̀dá Ti Pé Ọgọ́rùn-ún Ọdún Báyìí

Ó ti pé ọgọ́rùn-ún ọdún tá a kọ́kọ́ gbé sinimá “Photo-Drama of Creation” jáde, káwọn èèyàn lè gbà pé Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ni Bíbélì.

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Àwòkẹ́kọ̀ọ́ “Eureka” Mú Kí Ọ̀pọ̀ Rí Ẹ̀kọ́ Òtítọ́

Àwọn tó wà láwọn abúlé oko, kódà láwọn ibi tí kò sí iná mànàmáná lè wo àwòkẹ́kọ̀ọ́ tí kò gùn tó “Photo-Drama of Creation” yìí.

LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA

À Ń Wàásù Ìhìn Rere Lórí Rédíò Àti Tẹlifíṣọ̀n

Báwo làwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe lo iléeṣẹ́ rédíò WBBR láti wàásù ìhìn rere?