‘Dájúdájú Ọlọ́run Fi Í Ṣe Olúwa àti Kristi’
Bọ́jọ́ ṣe ń gorí ọjọ́, a lè bẹ̀rẹ̀ sí í ṣiyèméjì, kí ìgbàgbọ́ wa má sì lágbára mọ́. Mú kí ìgbàgbọ́ tó o ní nínú Jésù, Mèsáyà tí Ọlọ́run ṣèlérí àti Ọba Ìjọba Ọlọ́run túbọ̀ lágbára.
‘Dájúdájú Ọlọ́run Fi Í Ṣe Olúwa àti Kristi’ (Apá 1)
Kí ló mú kó dá ẹ lójú pé Ọlọ́run ti fi Jésù ṣe Olúwa àti Kristi?
‘Dájúdájú Ọlọ́run Fi Í Ṣe Olúwa àti Kristi’ (Apá 2)
Wàá rí ohun tó máa jẹ́ kó o nígbàgbọ́ tó lágbára nínú Jésù.