Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ẹ̀KỌ́ 14

Jẹ́ Kí Kókó Ọ̀rọ̀ Fara Hàn Kedere

Jẹ́ Kí Kókó Ọ̀rọ̀ Fara Hàn Kedere

Ṣó o fẹ́ fún àwọn èèyàn ní ìsọfúnni kan ni? Ṣó o fẹ́ fi nǹkan kan dá wọn lójú ni? Ṣó o fẹ́ gbà wọ́n níyànjú ni? Ohun tó máa jẹ́ kó o ṣàṣeyọrí ni pé kó o fara balẹ̀ yan àwọn kókó pàtàkì inú ọ̀rọ̀ rẹ̀, kó o sì tò wọ́n bó ṣe yẹ.