Nehemáyà: “Ìdùnnú Jèhófà Ni Ibi Ààbò Yín”

Nehemáyà darí àwọn èèyàn láti tún ògiri Jerúsálẹ́mù kọ́, ó sì mú ìjọsìn Jèhófà pa dà bọ̀ sípò.

Nehemáyà: “Ìdùnnú Jèhófà Ni Ibi Ààbò Yín”​—Apá Kìíní

Nehemáyà tún ògiri Jerúsálẹ́mù kọ́ láìka onírúurú àtakò tó dojú kọ.

Nehemáyà: “Ìdùnnú Jèhófà Ni Ibi Ààbò Yín”​—Apá Kejì

Wọ́n ti tún ògiri Jerúsálẹ́mù kọ́, àmọ́ ṣé Nehemáyà máa mú káwọn ọmọ Ísírẹ́lì tún pa dà máa sin Jèhófà bọ́ ṣe yẹ?