Nehemáyà: “Ìdùnnú Jèhófà Ni Ibi Ààbò Yín”—Apá Kejì
Lẹ́yìn tí wọ́n tún ògiri Jerúsálẹ́mù kọ́, Nehemáyà tún kojú ìṣòro míì. Ó kíyè sí i pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ò sin Jèhófà bó ṣe yẹ mọ́. Àmọ́ òun, Ẹ́sírà àti Málákì ṣe gbogbo ohun tí wọ́n lè ṣe kí ìjọsìn mímọ́ lè pa dà bọ̀ sípò.