Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Nehemáyà: “Ìdùnnú Jèhófà Ni Ibi Ààbò Yín”​—Apá Kìíní

Nehemáyà: “Ìdùnnú Jèhófà Ni Ibi Ààbò Yín”​—Apá Kìíní

Nehemáyà fi ipò tó wà láàfin ọba ní Ṣúṣánì sílẹ̀, kó lè lọ tún ògiri ìlú ńlá Jèhófà kọ́. Àmọ́, iṣẹ́ ìkọ́lé ńlá tí Nehemáyà fẹ́ ṣe yẹn nìkan kọ́ ló máa dán ìgbàgbọ́ rẹ̀ wò. Ṣé àdúrà tí Nehemáyà ń gbà àti bó ṣe nígboyà ti tó láti parí iṣẹ́ yìí?