Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Nóà—Ó Bá Ọlọ́run Rìn

Olóòótọ́ èèyàn tó bá Ọlọ́run rìn ni Nóà. Àmọ́ kí nìdí tí Ọlọ́run fi ṣojúure sí Nóà? Kí ló mú kí tiẹ̀ yàtọ̀? Wo bí ohun tí Nóà ṣe ṣe ṣe òun àti ìdílé rẹ̀ láǹfààní, títí kan gbogbo wa lónìí.

 

O Tún Lè Wo

KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ

Káàdì Eré Bíbélì Nípa Nóà

Ǹjẹ́ o mọ orúkọ àwọn ọmọkùnrin Nóà mẹ́tẹ̀ẹ̀ta? Mọ púpọ̀ sí i nípa Nóà àti ìdílé rẹ̀.

Ẹ̀kọ́ Bíbélì

Ọkọ̀ Nóà

Kọ́ àwọn ọmọ rẹ nípa àwọn ẹranko tó wà nínú ọkọ̀ Nóà.

ERÉ ALÁWÒRÁN

Kí Lá Rí Kọ́ Lára Nóà?

Wa eré yìí jáde, kó o sì tẹ̀ ẹ́, kí o sì wo bó o ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ ìgbọràn Nóà.