Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ọmọ Onínàákúnàá Pa Dà Wálé

Ọ̀dọ́kùnrin kan tí wọ́n tọ́ dàgbà nínú òtítọ́ bẹ̀rẹ̀ sí í bá àwọn ọ̀rẹ́ tí ìwà àti ìgbésí ayé wọn kò bá ìlànà Bíbélì mu kẹ́gbẹ́. Báwo ni ìgbé ayé tó bẹ̀rẹ̀ sí í gbé yìí ṣe rí lára àwọn ará ilé rẹ̀? Àwọn ẹ̀kọ́ wo la lè kọ́ látinú ìtàn tó jẹ́ ká rí àwọn ìṣòro táwọn ọ̀dọ́ ń kojú lóde òní?