“A Ò Ní Fi Falẹ̀ Mọ́”
Wo fídíò yìí kó o lè rí báwọn àsọtẹ́lẹ̀ amóríyá tó wà nínú ìwé Ìfihàn ṣe máa ṣẹ láìpẹ́, tíyẹn á wá mú ìtura wá fáwọn tó nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, táá sì mú kí ìdájọ́ òdodo wà títí láé. Ó dá lórí Ìfihàn 18:1–19:3; 19:11–20:3; 20:12-14; 22:1-7.