Jèhófà Máa Ń Gba Àwọn Èèyàn Rẹ̀ Sílẹ̀
Ìtàn tó wà nínú ìwé Ẹ́kísódù orí 3 sí 15 nínú Bíbélì fi hàn pé Ọlọ́run tó pín Òkun Pupa sí méjì máa gba ìwọ náà tó o bá nígbàgbọ́ nínú rẹ̀.
Ó dá lórí Ẹ́kísódù 3:1-22; 4:1-9; 5:1-9; 6:1-8; 7:1-7; 14:5-10, 13-31; 15:1-21.