Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

“Nítorí Èyí Ni Mo Ṣe Wá sí Ayé”

Wo ọ̀nà tó ṣàrà ọ̀tọ̀ tí Jésù ń gbà kọ́ni bó ṣe ń fìgboyà jẹ́rìí sí òtítọ́.

Ó dá lórí Mátíù 21:​23-46; 22:​15-46.

 

O Tún Lè Wo

JÉSÙ—Ọ̀NÀ, ÒTÍTỌ́ ÀTI ÌYÈ

Ìdáhùn Jésù Ò Jẹ́ Káwọn Ọ̀tá Rẹ̀ Rí I Mú

Jésù kọ́kọ́ pa àwọn Farisí lẹ́nu mọ́, lẹ́yìn náà àwọn Sadusí, nígbà tó yá, ó pa gbogbo àwọn alátakò rẹ̀ lẹ́nu mọ́.

JÉSÙ—Ọ̀NÀ, ÒTÍTỌ́ ÀTI ÌYÈ

Ó Dẹ́bi Fáwọn Aṣáájú Ìsìn Tó Ń Ta Kò Ó

Kí nìdí tí Jésù ò fi gbàgbàkugbà fún àwọn aṣáájú ìsìn yẹn?

JÉSÙ—Ọ̀NÀ, ÒTÍTỌ́ ÀTI ÌYÈ

Àpèjúwe Méjì Nípa Ọgbà Àjàrà

Wàá rí ìtumọ̀ àpèjúwe tí Jésù ṣe nípa bàbá kán tó ní kí ọmọ òun lọ ṣiṣẹ́ nínú ọgbà àjàrà àti àpèjúwe tó ṣe nípa ọkùnrin kan tó jẹ́ pé èèyàn burúkú làwọn tó ń bá a ṣiṣẹ́ nínú ọgbà àjàrà rẹ̀.

ÀWỌN FÍDÍÒ

‘Dájúdájú Ọlọ́run Fi Í Ṣe Olúwa àti Kristi’ (Apá 1)

Kí ló mú kó dá ẹ lójú pé Ọlọ́run ti fi Jésù ṣe Olúwa àti Kristi?

ÀWỌN FÍDÍÒ

‘Dájúdájú Ọlọ́run Fi Í Ṣe Olúwa àti Kristi’ (Apá 2)

Wàá rí ohun tó máa jẹ́ kó o nígbàgbọ́ tó lágbára nínú Jésù.