A6-A
Àtẹ: Àwọn Wòlíì àti Àwọn Ọba Ilẹ̀ Júdà àti Ísírẹ́lì (Apá Kìíní)
Àwọn Ọba Ìjọba Ẹ̀yà Méjì ti Júdà ní Gúúsù
997 Ṣ.S.K.
Rèhóbóámù: 17 ọdún
980
Ábíjà (Ábíjámù): 3 ọdún
978
Ásà: 41 ọdún
937
Jèhóṣáfátì: 25 ọdún
913
Jèhórámù: 8 ọdún
n. 906
Ahasáyà: 1 ọdún
n. 905
Ọbabìnrin Ataláyà: 6 ọdún
898
Jèhóáṣì: 40 ọdún
858
Amasááyà: 29 ọdún
829
Ùsáyà (Asaráyà): 52 ọdún
Àwọn Ọba Ìjọba Ẹ̀yà Mẹ́wàá ti Ísírẹ́lì ní Àríwá
997 Ṣ.S.K.
Jèróbóámù: 22 ọdún
n. 976
Nádábù: 2 ọdún
n. 975
Bááṣà: 24 ọdún
n. 952
Élà: 2 ọdún
Símírì: ọjọ́ 7 (n. 951)
Ómírì àti Tíbínì: 4 ọdún
n. 947
Ómírì (nìkan): 8 ọdún
n. 940
Áhábù: 22 ọdún
c. 920
Ahasáyà: 2 ọdún
n. 917
Jèhórámù: 12 ọdún
n. 905
Jéhù: 28 ọdún
876
Jèhóáhásì: 14 ọdún
n. 862
Jèhóáhásì àti Jèhóáṣì: 3 ọdún
n. 859
Jèhóáṣì (nìkan): 16 ọdún
n. 844
Jèróbóámù Kejì: 41 ọdún
-
Orúkọ Àwọn Wòlíì
-
Jóẹ́lì
-
Èlíjà
-
Èlíṣà
-
Jónà
-
Émọ́sì