A7-D
Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tó Ta Yọ Tí Jésù Ṣe ní Gálílì (Apá Kìíní)
ÀKÓKÒ |
IBI |
ÌṢẸ̀LẸ̀ |
MÁTÍÙ |
MÁÀKÙ |
LÚÙKÙ |
JÒHÁNÙ |
---|---|---|---|---|---|---|
30 |
Gálílì |
Ìgbà àkọ́kọ́ tí Jésù kéde pé “Ìjọba ọ̀run ti sún mọ́lé” |
||||
Kánà; Násárẹ́tì; Kápánáúmù |
Ó mú ọmọ òṣìṣẹ́ ọba kan lára dá; ó ka àkájọ ìwé Àìsáyà; ó lọ sí Kápánáúmù |
|||||
Òkun Gálílì, nítòsí Kápánáúmù |
Ó pe ọmọ ẹ̀yìn mẹ́rin: Símónì àti Áńdérù, Jémíìsì àti Jòhánù |
|||||
Kápánáúmù |
Ó mú ìyá ìyàwó Símónì àtàwọn míì lára dá |
|||||
Gálílì |
Ìrìn àjò àkọ́kọ́ ní Gálílì, pẹ̀lú ọmọ ẹ̀yìn mẹ́rin náà |
|||||
Ó wo adẹ́tẹ̀ sàn; àwọn èrò tẹ̀ lé e |
||||||
Kápánáúmù |
Ó wo alárùn rọpárọsẹ̀ kan sàn |
|||||
Ó pe Mátíù; ó bá àwọn agbowó orí jẹun; wọ́n béèrè ọ̀rọ̀ nípa ààwẹ̀ |
||||||
Jùdíà |
Ó wàásù nínú sínágọ́gù |
|||||
31, Ìrékọjá |
Jerúsálẹ́mù |
Ó wo ọkùnrin aláìsàn tó wà ní Bẹtisátà sàn; Àwọn Júù ń wá bí wọ́n ṣe máa pa á |
||||
Ó pa dà láti Jerúsálẹ́mù (?) |
Àwọn ọmọ ẹ̀yìn ń ya erín ọkà jẹ lọ́jọ́ Sábáàtì; Jésù “Olúwa Sábáàtì” |
|||||
Gálílì; Òkun Gálílì |
Ó mú ọkùnrin tí ọwọ́ rẹ̀ rọ lára dá lọ́jọ́ Sábáàtì; ọ̀pọ̀ èèyàn tẹ̀ lé e; ó wo ọ̀pọ̀ èèyàn sàn |
|||||
Òkè nítòsí Kápánáúmù |
Ó yan àpọ́sítélì méjìlá |
|||||
Nítòsí Kápánáúmù |
Ó ṣe Ìwàásù Lórí Òkè |
|||||
Kápánáúmù |
Ó wo ìránṣẹ́ ọ̀gágun kan sàn |
|||||
Náínì |
Ó jí ọmọ opó kan dìde |
|||||
Tìbéríà; Gálílì (Náínì tàbí nítòsí) |
Jòhánù rán àwọn ọmọ ẹ̀yìn sí Jésù; a ṣí òtítọ́ payá fún àwọn ọmọdé; àjàgà rọrùn |
|||||
Gálílì (Náínì tàbí nítòsí) |
Obìnrin ẹlẹ́ṣẹ̀ kan da òróró sí ẹsẹ̀ rẹ̀; àpèjúwe nípa àwọn ajigbèsè |
|||||
Gálílì |
Ìrìn àjò kejì lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù, pẹ̀lú àwọn méjìlá (12) náà |
|||||
Ó lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde; ẹ̀ṣẹ̀ tí kò ní ìdáríjì |
||||||
Àmì Jónà nìkan ló fún àwọn èèyàn |
||||||
Ìyá rẹ̀ àtàwọn àbúrò rẹ̀ wá; ó sọ pé àwọn ọmọ ẹ̀yìn ni ẹbí òun |