A7-G
Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Jésù Ṣe Kẹ́yìn ní Jerúsálẹ́mù (Apá Kìíní)
ÀKÓKÒ |
IBI |
ÌṢẸ̀LẸ̀ |
MÁTÍÙ |
MÁÀKÙ |
LÚÙKÙ |
JÒHÁNÙ |
---|---|---|---|---|---|---|
33, Nísàn 8 |
Bẹ́tánì |
Jésù dé lọ́jọ́ mẹ́fà ṣáájú Ìrékọjá |
||||
Nísàn 9 |
Bẹ́tánì |
Màríà da òróró sí orí àti ẹsẹ̀ rẹ̀ |
||||
Bẹ́tánì sí Bẹtifágè sí Jerúsálẹ́mù |
Ó wọ Jerúsálẹ́mù tiyì-tẹ̀yẹ, ó gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ |
|||||
Nísàn 10 |
Bẹ́tánì sí Jerúsálẹ́mù |
Ó gégùn-ún fún igi ọ̀pọ̀tọ́; ó fọ tẹ́ńpìlì mọ́ lẹ́ẹ̀kan sí i |
||||
Jerúsálẹ́mù |
Àwọn àlùfáà àgbà àtàwọn akọ̀wé òfin gbìmọ̀ pọ̀ láti pa Jésù |
|||||
Jèhófà sọ̀rọ̀; Jésù sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀; àsọtẹ́lẹ̀ tí Àìsáyà sọ nípa àìnígbàgbọ́ àwọn Júù ṣẹ |
||||||
Nísàn 11 |
Bẹ́tánì sí Jerúsálẹ́mù |
Ẹ̀kọ́ látara igi ọ̀pọ̀tọ́ tó rọ |
||||
Jerúsálẹ́mù, tẹ́ńpìlì |
Wọ́n béèrè ẹni tó fún Jésù láṣẹ; àpèjúwe ọmọkùnrin méjì |
|||||
Àwọn àpèjúwe: àwọn tó ń dáko tí wọ́n jẹ́ apààyàn, àsè ìgbéyàwó |
||||||
Ó dáhùn ìbéèrè nípa Ọlọ́run àti Késárì, àjíǹde, àṣẹ tó tóbi jù lọ |
||||||
Ó bi àwọn èrò bóyá Kristi jẹ́ ọmọ Dáfídì |
||||||
Àwọn akọ̀wé òfin àtàwọn Farisí gbé |
||||||
Ó kíyè sí ohun tí opó kan fi ṣètọrẹ |
||||||
Òkè Ólífì |
Ó sọ àmì ìgbà tí òun máa wà níhìn-ín |
|||||
Àwọn àpèjúwe: wúńdíá mẹ́wàá, tálẹ́ńtì, àgùntàn àti ewúrẹ́ |
||||||
Nísàn 12 |
Jerúsálẹ́mù |
Àwọn aṣáájú Júù gbìmọ̀ pọ̀ láti pa á |
||||
Júdásì ṣètò bó ṣe máa fà á lé wọn lọ́wọ́ |
||||||
Nísàn 13 (Ọ̀sán Thursday) |
Nítòsí àti nínú Jerúsálẹ́mù |
Ó múra sílẹ̀ fún Ìrékọjá tó ṣe kẹ́yìn |
||||
Nísàn 14 |
Jerúsálẹ́mù |
Ó bá àwọn àpọ́sítélì jẹ Ìrékọjá |
||||
Ó fọ ẹsẹ̀ àwọn àpọ́sítélì |