A7-Ẹ
Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tó Ta Yọ Tí Jésù Ṣe ní Gálílì (Apá Kẹta) àti ní Jùdíà
ÀKÓKÒ |
IBI |
ÌṢẸ̀LẸ̀ |
MÁTÍÙ |
MÁÀKÙ |
LÚÙKÙ |
JÒHÁNÙ |
---|---|---|---|---|---|---|
32, lẹ́yìn Ìrékọjá |
Òkun Gálílì; Bẹtisáídà |
Jésù wọkọ̀ ojú omi lọ sí Bẹtisáídà, ó kìlọ̀ nípa ìwúkàrà àwọn Farisí; ó la ojú ọkùnrin afọ́jú |
||||
Agbègbè Kesaríà ti Fílípì |
Àwọn kọ́kọ́rọ́ Ìjọba Ọlọ́run; ó sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú àti àjíǹde rẹ̀ |
|||||
Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ ní Òkè Hámónì |
Ìyípadà ológo; Jèhófà sọ̀rọ̀ |
|||||
gbègbè Kesaríà ti Fílípì |
Ó lé ẹ̀mí èṣù jáde lára ọmọkùnrin kan |
|||||
Gálílì |
Ó tún sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ |
|||||
Kápánáúmù |
Ó fi owó tí wọ́n rí lẹ́nu ẹja san owó orí |
|||||
Ẹni tó tóbi jù nínú Ìjọba Ọlọ́run; àpèjúwe àgùntàn tó sọ nù àti ti ẹrú tí kò dárí jini |
||||||
Gálílì sí Samáríà |
Ó ń lọ sí Jerúsálẹ́mù, ó sọ fáwọn ọmọ ẹ̀yìn pé kí wọ́n yááfì gbogbo nǹkan torí Ìjọba Ọlọ́run |
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Jésù Tún Ṣe ní Jùdíà
ÀKÓKÒ |
IBI |
ÌṢẸ̀LẸ̀ |
MÁTÍÙ |
MÁÀKÙ |
LÚÙKÙ |
JÒHÁNÙ |
---|---|---|---|---|---|---|
32, Àjọyọ̀ Àwọn Àgọ́ Ìjọsìn (tàbí Àtíbàbà) |
Jerúsálẹ́mù |
Ó kọ́ni níbi Àjọyọ̀ náà; wọ́n rán àwọn òṣìṣẹ́ pé kí wọ́n wá mú un |
||||
Ó sọ pé “Èmi ni ìmọ́lẹ̀ ayé”; ó la ojú ọkùnrin tí wọ́n bí ní afọ́jú |
||||||
Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ ní Jùdíà |
Ó rán àwọn 70 jáde; wọ́n pa dà dé tayọ̀tayọ̀ |
|||||
Jùdíà; Bẹ́tánì |
Àpèjúwe ará Samáríà tó nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ̀; ó lọ sí ilé Màríà àti Màtá |
|||||
Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ ní Jùdíà |
Ó tún kọ́ wọn ní àdúrà àwòṣe; àpèjúwe ọ̀rẹ́ kan tí kò yéé bẹ̀bẹ̀ |
|||||
Ó fi ìka Ọlọ́run lé ẹ̀mí èṣù jáde; ó tún fún wọn ní àmì Jónà nìkan |
||||||
Ó bá Farisí jẹun; ó dẹ́bi fún ìwà àgàbàgebè àwọn Farisí |
||||||
Àwọn àpèjúwe: ọkùnrin ọlọ́rọ̀ tó jẹ́ aláìlóye àti ti ìríjú olóòótọ́ náà |
||||||
Lọ́jọ́ Sábáàtì, ó wo obìnrin kan tí kò lè nàró sàn; àpèjúwe hóró músítádì àti ti ìwúkàrà |
||||||
32, Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́ |
Jerúsálẹ́mù |
Jerúsálẹ́mù Àpèjúwe olùṣọ́ àgùntàn àtàtà àti agbo àgùntàn; àwọn Júù fẹ́ sọ ọ́ lókùúta; ó kọjá sí Bẹ́tánì ní òdìkejì Jọ́dánì |