B14-A
Òwò àti Ọrọ̀ Ajé
-
Òṣùwọ̀n Nǹkan Olómi
-
Kọ́ọ̀ (Báàtì 10 / Hínì 60)
Lítà 220 / Gálọ́ọ̀nù 58.1
-
Báàtì (Hínì 6)
Lítà 22 / Gálọ́ọ̀nù 5.81
-
Hínì (Lọ́ọ̀gì 12)
Lítà 3.67 / Páìntì 7.75
-
Lọ́ọ̀gì (Hínì 1 ⁄ 12)
Lítà 0.31 / Páìntì 0.66
-
Òṣùwọ̀n Nǹkan Gbígbẹ
-
Hómérì (Kọ́ọ̀ 1 / Eéfà 10)
Lítà 220 /Kúọ̀tì 200
-
Eéfà (Síà 3 / Ómérì 10)
Lítà 22 /Kúọ̀tì 20
-
Síà (Ómérì 31 ⁄ 3)
Lítà 7.33 / Kúọ̀tì 6.66
-
Ómérì (Káàbù 14 ⁄ 5)
Lítà 2.2 / Kúọ̀tì 2
-
Káàbù
Lítà 1.22 / Kúọ̀tì 1.11
-
Kúọ̀tì
Lítà 1.08 / Kúọ̀tì 0.98
-
Ìdíwọ̀n Nǹkan Gbọọrọ
-
Ọ̀pá esùsú gígùn (Ìgbọ̀nwọ́ gígùn 6)
Mítà 3.11 / Ẹsẹ̀ bàtà 10.2
-
Esùsú (Ìgbọ̀nwọ́ 6)
Mítà 2.67 / Ẹsẹ̀ bàtà 8.75
-
Fátọ́ọ̀mù
Mítà 1.8 / Ẹsẹ̀ bàtà 6
-
Ìgbọ̀nwọ́ gígùn (Ìbú ọwọ́ 7)
Sẹ̀ǹtímítà 51.8 / Ínǹṣì 20.4
-
Ìgbọ̀nwọ́ (Ìbú àtẹ́lẹwọ́ 2 / Ìbú ọwọ́ 6)
Sẹ̀ǹtímítà 44.5 / Ínǹṣì 17.5
-
Ìgbọ̀nwọ́ kékeré
Sẹ̀ǹtímítà 38 / Ínǹṣì 15
-
Sítédíọ̀mù Róòmù 1
Máìlì Róòmù 1 ⁄ 8= Mítà 185 / Ẹsẹ̀ bàtà 606.95
-
1 Ìbú ìka (Ìbú ọwọ́ 1 ⁄ 4)
Sẹ̀ǹtímítà 1.85 / Ínǹṣì 0.73
-
2 Ìbú ọwọ́ (Ìbú ìka 4)
Sẹ̀ǹtímítà 7.4 / Ínǹṣì 2.9
-
3 Ìbú àtẹ́lẹwọ́ (Ìbú ọwọ́ 3)
Sẹ̀ǹtímítà 22.2 / Ínǹṣì 8.75