Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àtẹ Àwọn Ìwé Inú Bíbélì

Àwọn Ìwé inú Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù Ṣáájú Sànmánì (Kristẹni)

ORÚKỌ ÌWÉ

ÒǸKỌ̀WÉ

IBI TÍ A TI KỌ Ọ́

ÌGBÀ TÓ PARÍ (Ṣ.S.K.)

ÀKÓKÒ TÓ GBÀ (Ṣ.S.K.)

Jẹ́nẹ́sísì

Mósè

Aginjù

1513

“Ní ìbẹ̀rẹ̀” sí 1657

Ẹ́kísódù

Mósè

Aginjù

1512

1657 sí 1512

Léfítíkù

Mósè

Aginjù

1512

Oṣù kan (1512)

Nọ́ńbà

Mósè

Aginjù àti Pẹ̀tẹ́lẹ̀ Móábù

1473

1512 sí 1473

Diutarónómì

Mósè

Pẹ̀tẹ́lẹ̀ Móábù

1473

Oṣù méjì (1473)

Jóṣúà

Jóṣúà

Kénáánì

n. 1450

1473 sí n. 1450

Àwọn Onídàájọ́

Sámúẹ́lì

Ísírẹ́lì

n. 1100

n. 1450 sí n. 1120

Rúùtù

Sámúẹ́lì

Ísírẹ́lì

n. 1090

11 ọdún ìṣàkóso Àwọn Onídàájọ́

1 Sámúẹ́lì

Sámúẹ́lì; Gádì; Nátánì

Ísírẹ́lì

n. 1078

n. 1180 sí 1078

2 Sámúẹ́lì

Gádì; Nátánì

Ísírẹ́lì

n. 1040

1077 sí n. 1040

1 Àwọn Ọba

Jeremáyà

Júdà

580

n. 1040 sí 911

2 Àwọn Ọba

Jeremáyà

Júdà àti Íjíbítì

580

n. 920 sí 580

1 Kíróníkà

Ẹ́sírà

Jerúsálẹ́mù (?)

n. 460

Lẹ́yìn 1 Kíróníkà 9:44: n. 1077 sí 1037

2 Kíróníkà

Ẹ́sírà

Jerúsálẹ́mù (?)

n. 460

n. 1037 sí 537

Ẹ́sírà

Ẹ́sírà

Jerúsálẹ́mù

n. 460

537 sí n. 467

Nehemáyà

Nehemáyà

Jerúsálẹ́mù

l. 443

456 sí l. 443

Ẹ́sítà

Módékáì

Ṣúṣánì, Élámù

n. 475

493 sí n. 475

Jóòbù

Mósè

Aginjù

n. 1473

Ó ju 140 ọdún láti 1657 sí 1473

Sáàmù

Dáfídì àti àwọn míì

 

n. 460

 

Òwe

Sólómọ́nì; Ágúrì; Lémúẹ́lì

Jerúsálẹ́mù

n. 717

 

Oníwàásù

Sólómọ́nì

Jerúsálẹ́mù

ṣ. 1000

 

Orin Sólómọ́nì

Sólómọ́nì

Jerúsálẹ́mù

n. 1020

 

Àìsáyà

Àìsáyà

Jerúsálẹ́mù

l. 732

n. 778 sí l. 732

Jeremáyà

Jeremáyà

Júdà; Íjíbítì

580

647 sí 580

Ìdárò

Jeremáyà

Nítòsí Jerúsálẹ́mù

607

 

Ìsíkíẹ́lì

Ìsíkíẹ́lì

Bábílónì

n. 591

613 sí n. 591

Dáníẹ́lì

Dáníẹ́lì

Bábílónì

n. 536

618 sí n. 536

Hósíà

Hósíà

Samáríà (Agbègbè)

l. 745

ṣ. 804 sí l. 745

Jóẹ́lì

Jóẹ́lì

Júdà

n. 820 (?)

 

Émọ́sì

Émọ́sì

Júdà

n. 804

 

Ọbadáyà

Ọbadáyà

 

n. 607

 

Jónà

Jónà

 

n. 844

 

Míkà

Míkà

Júdà

ṣ. 717

n. 777 si 717

Náhúmù

Náhúmù

Júdà

ṣ. 632

 

Hábákúkù

Hábákúkù

Júdà

n. 628 (?)

 

Sefanáyà

Sefanáyà

Júdà

ṣ. 648

 

Hágáì

Hágáì

Jerúsálẹ́mù

520

112 ọjọ́ (520)

Sekaráyà

Sekaráyà

Jerúsálẹ́mù

518

520 sí 518

Málákì

Málákì

Jerúsálẹ́mù

l. 443

 

Àwọn Ìwé inú Ìwé Mímọ́ Lédè Gíríìkì Tí A Kọ ní Sànmánì (Kristẹni)

ORÚKỌ ÌWÉ

ÒǸKỌ̀WÉ

IBI TÍ A TI KỌ Ọ́

ÌGBÀ TÓ PARÍ (S.K.)

ÀKÓKÒ TÓ GBÀ

Mátíù

Mátíù

Ísírẹ́lì

n. 41

2 Ṣ.S.K. sí 33 S.K.

Máàkù

Máàkù

Róòmù

n. 60 sí 65

29 sí 33 S.K.

Lúùkù

Lúùkù

Kesaríà

n. 56 sí 58

3 Ṣ.S.K. sí 33 S.K.

Jòhánù

Àpọ́sítélì Jòhánù

Éfésù tàbí nítòsí

n. 98

Lẹ́yìn ìṣẹ̀lẹ̀ ìṣáájú, 29 sí 33 S.K.

Ìṣe

Lúùkù

Róòmù

n. 61

33 sí n. 61 S.K.

Róòmù

Pọ́ọ̀lù

Kọ́ríńtì

n. 56

 

1 Kọ́ríńtì

Pọ́ọ̀lù

Éfésù

n. 55

 

2 Kọ́ríńtì

Pọ́ọ̀lù

Makedóníà

n. 55

 

Gálátíà

Pọ́ọ̀lù

Kọ́ríńtì tàbí Áńtíókù ti Síríà

n. 50 sí 52

 

Éfésù

Pọ́ọ̀lù

Róòmù

n. 60 sí 61

 

Fílípì

Pọ́ọ̀lù

Róòmù

n. 60 sí 61

 

Kólósè

Pọ́ọ̀lù

Róòmù

c. 60 sí 61

 

1 Tẹsalóníkà

Pọ́ọ̀lù

Kọ́ríńtì

n. 50

 

2 Tẹsalóníkà

Pọ́ọ̀lù

Kọ́ríńtì

n. 51

 

1 Tímótì

Pọ́ọ̀lù

Makedóníà

n. 61 sí 64

 

2 Tímótì

Pọ́ọ̀lù

Róòmù

n. 65

 

Títù

Pọ́ọ̀lù

Makedóníà (?)

n. 61 sí 64

 

Fílémónì

Pọ́ọ̀lù

Róòmù

n. 60 sí 61

 

Hébérù

Pọ́ọ̀lù

Róòmù

n. 61

 

Jémíìsì

Jémíìsì (Àbúrò Jésù)

Jerúsálẹ́mù

ṣ. 62

 

1 Pétérù

Pétérù

Bábílónì

n. 62 sí 64

 

2 Pétérù

Pétérù

Bábílónì (?)

n. 64

 

1 Jòhánù

Àpọ́sítélì Jòhánù

Éfésù tàbí nítòsí

n. 98

 

2 Jòhánù

Àpọ́sítélì Jòhánù

Éfésù tàbí nítòsí

n. 98

 

3 Jòhánù

Àpọ́sítélì Jòhánù

Éfésù tàbí nítòsí

n. 98

 

Júùdù

Júùdù (Àbúrò Jésù))

Ísírẹ́lì (?)

n. 65

 

Ìfihàn

Àpọ́sítélì Jòhánù

Pátímọ́sì

n. 96

 

[Orúkọ àwọn òǹkọ̀wé ìwé mélòó kan àti ibi tí a ti kọ wọ́n kò dájú. Ṣe ni a fojú bu ọ̀pọ̀ nínú àwọn déètì náà, àmì náà l. túmọ̀ sí “lẹ́yìn,” n. túmọ̀ sí “nǹkan bí,” ṣ. sì túmọ̀ sí “ṣáájú.”]