YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 Ìwé Ẹ́sítà Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Ọba Ahasuérúsì se àsè ńlá ní Ṣúṣánì (1-9) Fáṣítì Ayaba kò ṣègbọràn (10-12) Ọba fọ̀rọ̀ lọ àwọn amòye rẹ̀ (13-20) Wọ́n fi àṣẹ ọba ránṣẹ́ (21, 22) 2 Wọ́n wá ayaba tuntun (1-14) Ẹ́sítà di ayaba (15-20) Módékáì tú àṣírí àwọn ọlọ̀tẹ̀ (21-23) 3 Ọba gbé Hámánì ga (1-4) Hámánì gbèrò láti pa àwọn Júù run (5-15) 4 Módékáì ṣọ̀fọ̀ (1-5) Módékáì ní kí Ẹ́sítà bá àwọn bẹ ọba (6-17) 5 Ẹ́sítà wá síwájú ọba (1-8) Hámánì ń bínú, ó sì ń gbéra ga (9-14) 6 Ọba dá Módékáì lọ́lá (1-14) 7 Ẹ́sítà tú Hámánì fó (1-6a) Wọ́n gbé Hámánì kọ́ sórí òpó igi tó ṣe (6b-10) 8 Ọba gbé Módékáì ga (1, 2) Ẹ́sítà bẹ ọba (3-6) Àṣẹ tí ọba fi ta ko àṣẹ àkọ́kọ́ (7-14) Àwọn Júù rí ìtura, wọ́n sì ń yọ̀ (15-17) 9 Àwọn Júù ṣẹ́gun (1-19) Wọ́n dá àjọyọ̀ Púrímù sílẹ̀ (20-32) 10 Módékáì di ẹni ńlá (1-3) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Ẹ́sítà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) Ẹ́sítà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá Ẹ́sítà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt Ẹ́sítérì ojú ìwé 678