YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 Ìwé Málákì Orí 1 2 3 4 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Jèhófà nífẹ̀ẹ́ àwọn èèyàn rẹ̀ (1-5) Àwọn àlùfáà ń fi ẹran tó lábùkù rúbọ (6-14) Wọ́n á gbé orúkọ Ọlọ́run ga láàárín àwọn orílẹ̀-èdè (11) 2 Àwọn àlùfáà ò kọ́ àwọn èèyàn (1-9) Ó yẹ kí ìmọ̀ máa wà ní ètè àwọn àlùfáà (7) Àwọn èèyàn jẹ̀bi ìkọ̀sílẹ̀ tí kò tọ́ (10-17) “‘Mo kórìíra ìkọ̀sílẹ̀,’ ni Jèhófà” wí (16) 3 Olúwa tòótọ́ wá fọ tẹ́ńpìlì rẹ̀ mọ́ (1-5) Ìránṣẹ́ májẹ̀mú náà (1) Jèhófà rọ àwọn èèyàn pé kí wọ́n pa dà sọ́dọ̀ òun (6-12) Jèhófà kì í yí pa dà (6) “Ẹ pa dà sọ́dọ̀ mi, èmi yóò sì pa dà sọ́dọ̀ yín” (7) ‘Ẹ mú gbogbo ìdá mẹ́wàá wá, Jèhófà yóò sì tú ìbùkún sórí yín’ (10) Olódodo àti ẹni burúkú (13-18) Wọ́n kọ ìwé ìrántí kan níwájú Ọlọ́run (16) Ìyàtọ̀ láàárín olódodo àti ẹni burúkú (18) 4 Èlíjà yóò wá kí ọjọ́ Jèhófà tó dé (1-6) “Oòrùn òdodo yóò ràn” (2) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Málákì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) Málákì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá Málákì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt Málákì ojú ìwé 1293-1294