Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

April 18 sí 24

JÓÒBÙ 28-32

April 18 sí 24
  • Orin 17 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 115

  • Kẹ́kọ̀ọ́ Nínú Àpẹẹrẹ Ìwà Títọ́ Àwọn Ẹlòmíì (1Pe 5:9): (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Harold King: Ó Di Ìṣòtítọ́ Rẹ̀ Mú Lọ́gbà Ẹ̀wọ̀n. (Lọ sí home kó o wá wo abẹ́ WO FÍDÍÒ LÓRÍṢIRÍṢI > ÌFỌ̀RỌ̀WÁNILẸ́NUWÒ ÀTI ÌRÍRÍ.) Lẹ́yìn náà, jíròrò àwọn ìbéèrè yìí: Kí ni Arákùnrin King ṣe nígbà tó wà lẹ́wọ̀n tí ipò tẹ̀mí rẹ̀ kò fi jó rẹ̀yìn? Báwo ni kíkọ àwọn orin Ìjọba Ọlọ́run ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ láti fara da ipò tí kò rọgbọ tá a bá wà? Báwo ni bí Arákùnrin King ṣe fi òótọ́ sìn Jèhófà ṣe fún ọ lókun?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: ia orí 13 ìpínrọ̀ 13 sí 25, àtúnyẹ̀wò tó wà lójú ìwé 114 (30 min.)

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀)

  • Orin 81 àti Àdúrà