Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

April 23-​29

MÁÀKÙ 3-4

April 23-​29
  • Orin 77 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Jésù Ṣe Ìwòsàn ní Ọjọ́ Sábáàtì”: (10 min.)

    • Mk 3:1, 2​—Àwọn aṣáájú ẹ̀sìn Júù ń ṣọ́ Jésù, kí wọ́n lè wá ẹ̀sùn sí i lẹ́sẹ̀ (jy 78 ¶1-2)

    • Mk 3:3, 4​—Jésù mọ̀ pé wọ́n ní èrò òdì tí kò bá Ìwé Mímọ́ mu nípa òfin Sábáàtì (jy 78 ¶3)

    • Mk 3:5​—Jésù ní “ẹ̀dùn-ọkàn gidigidi sí yíyigbì ọkàn-àyà wọn” (“pẹ̀lú ìkannú, nítorí tí ó ní ẹ̀dùn-ọkàn gidigidi” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mr 3:5, nwtsty)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Mk 3:29​—Kí ló túmọ̀ sí láti sọ̀rọ̀ òdì sí ẹ̀mí mímọ́, kí sì ni ṣíṣe bẹ́ẹ̀ máa yọrí sí? (“ọ̀rọ̀ òdì sí ẹ̀mí mímọ́,” “ó jẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ àìnípẹ̀kun” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mr 3:29, nwtsty)

    • Mk 4:26-29​—Kí la lè rí kọ́ nínú àpèjúwe Jésù nípa afúnrúgbìn tó sùn? (w14 12/15 12-13 ¶6-8)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mk 3:​1-19a

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ.

  • Ìpadàbẹ̀wò Kẹta: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwọ ni kó o yan ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tó o máa lò, fi ọ̀kan nínú àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ lọ̀ ọ́.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 34-36 ¶21-22​—Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI