Jésù Ní Agbára Láti Jí Àwọn Èèyàn Wa Tó Kú Dìde
-
Tá a bá sunkún nígbà tí èèyàn wa bá kú, ìyẹn ò fi hàn pé a ò ní ìgbàgbọ́ nínú àjíǹde (Jẹ 23:2)
-
A máa túbọ̀ nígbàgbọ́ nínú àjíǹde tó ń bọ̀ lọ́jọ́ iwájú, tá a bá ń ronú lórí àwọn àjíǹde tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa ẹ̀
Ta lò ń fojú sọ́nà láti rí nígbà àjíǹde?
Báwo ló ṣe máa rí lára ẹ tẹ́ ẹ bá pa dà ríra?