Wọ́n ń kí ẹni tuntun kan káàbọ̀ sí Ìrántí Ikú Kristi

ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI April 2019

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ìjíròrò tó dá lórí ikú Jésù Kristi.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ẹ̀bùn Ni Wíwà Láìní Ọkọ Tàbí Aya

Báwo ni àwọn Kristẹni tí kò tí ì ṣègbéyàwó ṣe lè lo ẹ̀bùn tí wọ́n ní yìí dáadáa?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Jẹ́ Olóòótọ́

Nígbà tí àdánwò bá dé, Jèhófà máa fún wa ní ohun tá a nílò láti lè fara dà á.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Báwo Lo Ṣe Lè Múra Sílẹ̀ fún Ìrántí Ikú Kristi?

Ó yẹ kí gbogbo wa múra ọkàn wa sílẹ̀. Báwo la ṣe lè ṣe bẹ́ẹ̀?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ọlọ́run Máa Di “Ohun Gbogbo fún Kálukú”

Ọjọ́ ọ̀la ológo ń dúró de àwọn tó bá jẹ́ olóòótọ́ sí Jèhófà.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà​—“Ọlọ́run Ìtùnú Gbogbo”

Ìjọ Kristẹni jẹ́ ọ̀nà kan tí Jèhófà gbà ń tù wá nínú.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ẹ̀kọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ni Kó O Máa Lé

Olùkọ́ Atóbilọ́lá ni Jèhófà, ó ń fún wa ní ẹ̀kọ́ tó dáa jù lọ.