Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 2 KỌ́RÍŃTÌ 1-3

Jèhófà​—“Ọlọ́run Ìtùnú Gbogbo”

Jèhófà​—“Ọlọ́run Ìtùnú Gbogbo”

1:3, 4

Ìjọ Kristẹni jẹ́ ọ̀nà kan tí Jèhófà gbà ń tù wá nínú. Kí làwọn nǹkan tá a lè ṣe láti tu àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ nínú?

  • Tẹ́tí sí wọn, má dá ọ̀rọ̀ mọ́ wọn lẹ́nu

  • “Ẹ máa sunkún pẹ̀lú àwọn tó ń sunkún.”​—Ro 12:15

  • O lè kọ ọ̀rọ̀ tó ń gbéni ró sínú káàdì, kó o sì fún wọn, o sì lè fi ọ̀rọ̀ ránṣẹ́ sí wọn lórí fóònù tàbí kọ̀ǹpútà.​—w17.07 15, àpótí

  • Gbàdúrà fún wọn, kó o sì gbàdúrà pẹ̀lú wọn