Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

April 8-​14

1 KỌ́RÍŃTÌ 10-13

April 8-​14
  • Orin 30 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Jèhófà Jẹ́ Olóòótọ́”: (10 min.)

    • 1Kọ 10:13​—Jèhófà kọ́ ló ń fa àwọn àdánwò tó ń dé bá wa (w17.02 29-30)

    • 1Kọ 10:13​—Irú àwọn àdánwò tó “máa ń ṣẹlẹ̀ sí àwọn èèyàn” ló máa ń ṣẹlẹ̀ sí àwa náà

    • 1Kọ 10:13​—Tá a bá gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, ó máa ràn wá lọ́wọ́ ká lè fara da àdánwò yòówù kó dé bá wa

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • 1Kọ 10:8​—Kí nìdí tí ẹsẹ yìí fi sọ pé ẹgbẹ̀rún mẹ́tàlélógún (23,000) nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ló kú lọ́jọ́ kan ṣoṣo nígbà tí Nọ́ńbà 25:9 sọ pé ọ̀kẹ́ kan ó lé ẹgbàajì (24,000) ni? (w04 4/1 29)

    • 1Kọ 11:​5, 6, 10​—Ǹjẹ́ ó yẹ kí arábìnrin kan borí rẹ̀ tó bá ń darí ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì níbi tí arákùnrin wà? (w15 2/15 30)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Kọ 10:​1-17 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 25

  • Gbogbo Àwọn Ẹ̀yà Ara Jẹ́ Kò-Ṣeé-Má-Nìí’ (1Kọ 12:22): (10 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà.

  • Báwo Lo Ṣe Lè Múra Sílẹ̀ fún Ìrántí Ikú Kristi?”: (5 min.) Àsọyé. Rọ àwọn ará pé kí wọ́n fi àsìkò Ìrántí Ikú Kristi ronú lórí ìfẹ́ tí Jèhófà àti Jésù ní sí wa, kí wọ́n sì túbọ̀ mọyì ìfẹ́ tí àwọn méjèèjì ní sí wa.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 4 ¶15-22

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 31 àti Àdúrà