Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

April 27–May 3

JẸ́NẸ́SÍSÌ 34-35

April 27–May 3
  •  Orin 28 àti Àdúrà

  •  Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Àkóbá Tí Ẹgbẹ́ Búburú Máa Ń Fà”: (10 min.)

    • Jẹ 34:1​—Léraléra ni Dínà ń lọ sọ́dọ̀ àwọn ọmọbìnrin ilẹ̀ Kénáánì (w97 2/1 30 ¶4)

    • Jẹ 34:2​—Ṣékémù fipá bá Dínà lò pọ̀ (lv 103 ¶14)

    • Jẹ 34:7, 25​—Síméónì àti Léfì pa Ṣékémù àti gbogbo ọkùnrin to wà ní ìlú yẹn (w09 9/1 21 ¶1-2)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Jẹ 35:8​—Ta ni Dèbórà, kí la sì lè kọ́ lára rẹ̀? (it-1 600 ¶4)

    • Jẹ 35:22-26​—Báwo la ṣe mọ̀ pé kò pọn dandan kí ìlà ìdílé tí Mèsáyà ti wá gba ọ̀dọ̀ àkọ́bí kọjá? (w17.12 14)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 34:1-19 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI