August 15 Sí 21
SÁÀMÙ 102-105
Orin 80 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jèhófà Máa Ń Rántí Pé Ekuru Ni Wá”: (10 min.)
Sm 103:
8-12 —Jèhófà máa ń ṣàánú wa tá a bá ronú pìwà dà, ó sì máa ń dárí jì wá (w13 6/15 ojú ìwé 20 ìpínrọ̀ 14; w12 7/15 ojú ìwé 16 ìpínrọ̀ 17) Sm 103:
13, 14 —Jèhófà mọ ibi tí agbára wa mọ (w15 4/15 ojú ìwé 26 ìpínrọ̀ 8; w13 6/15 ojú ìwé 15 ìpínrọ̀ 16) Sm 103:
19, 22 —Tá a bá mọyì àánú àti inú rere onífẹ̀ẹ́ Jèhófà, a ó máa ti ipò ọba aláṣẹ rẹ̀ lẹ́yìn (w10 11/15 ojú ìwé 25 ìpínrọ̀ 5; w07 12/1 ojú ìwé 21 ìpínrọ̀ 1)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Sm 102:
12, 27 —Nígbà tí ìbànújẹ́ bá dorí wa kodò, báwo ni àjọṣe tá a ní pẹ̀lú Jèhófà ṣe lè ràn wá lọ́wọ́? (w14 3/15 ojú ìwé 16 ìpínrọ̀ 19 sí 21) Sm 103:13
—Kí nìdí tó fi jẹ́ pé kì í ṣe gbogbo àdúrà wa ni Jèhófà máa ń dáhùn lójú ẹsẹ̀? (w15 4/15 ojú ìwé 25 ìpínrọ̀ 7) Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?
Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 105:
24-45
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) g16.4 ojú ìwé 10 àti 11
—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá pa dà wá. Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) g16.4 ojú ìwé 10 àti 11
—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 164 sí 166 ìpínrọ̀ 3 àti 4
—Ran akẹ́kọ̀ọ́ náà lọ́wọ́ kó lè rí bó ṣe lè fi ohun tó kọ́ sílò.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Orin 91
Má Ṣe Gbàgbé Gbogbo Ohun Tí Jèhófà Ti Ṣe fún Ọ (Sm 103:
1-5): (15 min.) Ìjíròrò. Kọ́kọ́ fi fídíò tó wà lórí ìkànnì jw.org/yo han àwọn ará. Àkọlé fídíò náà ni Ọ̀rọ̀ Ara Mi Sú Mi. (Wo abẹ́ NÍPA WA > OHUN TÁ À Ń ṢE.) Lẹ́yìn náà ẹ jíròrò àwọn ìbéèrè yìí: Kí nìdí tó fi yẹ ká máa yin Jèhófà? Nítorí inú rere Jèhófà, àwọn ìbùkún ọjọ́ iwájú wo là ń retí? Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 22 ìpínrọ̀ 1 sí 13
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 131 àti Àdúrà