August 22 Sí 28
SÁÀMÙ 106-109
Orin 2 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ẹ Fi Ọpẹ́ Fún Jèhófà”: (10 min.)
Sm 106:
1-3 —Jèhófà ni ọpẹ́ wa tọ́ sí (w15 1/15 ojú ìwé 8 ìpínrọ̀ 1; w02 6/1 ojú ìwé 18 ìpínrọ̀ 19) Sm 106:
7-14, 19-25, 35-39 —Bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ò ṣe moore sọ wọ́n di aláìnígbàgbọ́ (w15 1/15 ojú ìwé 8 àti 9 ìpínrọ̀ 2 àti 3; w01 6/15 ojú ìwé 13 ìpínrọ̀ 1 sí 3) Sm 106:
4, 5, 48 —Ọ̀pọ̀ nǹkan ni Jèhófà ti ṣe fún wa tó yẹ ká máa dúpẹ́ fún (w11 10/15 ojú ìwé 5 ìpínrọ̀ 7; w03 12/1 ojú ìwé 15 àti 16 ìpínrọ̀ 3 sí 6)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Sm 109:8
—Ṣé Ọlọ́run ló kádàrá Júdásì pé kó da Jésù kí àsọtẹ́lẹ̀ lè ṣẹ? (w00 12/15 ojú ìwé 24 ìpínrọ̀ 20; it-1-E ojú ìwé 857 àti 858) Sm 109:31
—Báwo ni Jèhófà ṣe “dúró ní ọwọ́ ọ̀tún òtòṣì”? (w06 9/1 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 8) Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?
Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 106:
1-22
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) ll ojú ìwé 6
—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá pa dà wá. Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) ll ojú ìwé 7
—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 178 sí 179 ìpínrọ̀ 14 sí 16
—Ran akẹ́kọ̀ọ́ náà lọ́wọ́ kó lè rí bó ṣe lè fi ohun tó kọ́ sílò.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Orin 94
Jèhófà Á Bójú Tó Àwọn Ohun Tá A Nílò (Sm 107:9): (15 min.) Ìjíròrò. Kọ́kọ́ fi fídíò tá a pé àkọlé rẹ̀ ní Jèhófà Á Bójú Tó Àwọn Ohun Tá A Nílò han àwọn ará. (Lọ sí tv.pr418.com/yo, kó o sì wo abẹ́ WO FÍDÍÒ LÓRÍṢIRÍṢI > ÌDÍLÉ.) Ní kí àwọn ará sọ ẹ̀kọ́ pàtàkì tí wọ́n rí kọ́.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 22 ìpínrọ̀ 14 sí 24 àti àtúnyẹ̀wò tó wà lójú ìwé 194
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 149 àti Àdúrà