Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

August 29 Sí September 4

SÁÀMÙ 110-118

August 29 Sí September 4
  • Orin 61 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) ll ojú ìwé 16—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá pa dà wá.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) ll ojú ìwé 17—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 179 àti 180 ìpínrọ̀ 17 sí 19—Ran akẹ́kọ̀ọ́ náà lọ́wọ́ kó lè rí bó ṣe lè fi ohun tó kọ́ sílò.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 82

  • Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni”: (7 min.) Ìjíròrò.

  • Àkànṣe Ìwàásù Láti Pín Ìwé Ìròyìn Ilé Ìṣọ́ Lóṣù September”: (8 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo àkọ́kọ́ nínú àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tá a lè lò ní oṣù September kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì tó wà níbẹ̀. Ṣe iṣẹ́ yìí lọ́nà táá mú kí àwọn ará fi ìtara kọ́wọ́ ti àkànṣe ìwàásù yìí, sì gbà wọ́n níyànjú láti ṣe olùrànlọ́wọ́ aṣáájú-ọ̀nà.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia ojú ìwé 23 ìpínrọ̀ 1 sí 14

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 144 àti Àdúrà

    Ìránnilétí: Jọ̀wọ́ jẹ́ kí àwọn ará kọ́kọ́ gbọ́ orin tuntun yìí lẹ́ẹ̀kan, lẹ́yìn náà, kí ẹ kọ ọ́.