“Kí Ni Èmi Yóò San Pa Dà Fún Jèhófà?”
Onísáàmù náà mọ rírì Jèhófà gan-an ni, ìdí sì ni pé Jèhófà kó o yọ nínú “ìjàrá ikú.” (Sm 116:3) Láti fi hàn pé ó mọ rírì Jèhófà, ó pinnu pé òun máa mú gbogbo ìlérí òun ṣẹ̀ àti pé gbogbo ohun tí Jèhófà bá ní kí oun ṣe lòun máa ṣe.
Kí nìdí tó fi yẹ kí n mọ rírì Jèhófà lọ́sẹ̀ yìí?
Báwo ni mo ṣe lè fi hàn pé mo mọ rírì Jèhófà?