Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

August 8 Sí 14

SÁÀMÙ 92-101

August 8 Sí 14
  • Orin 28 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 90

  • Ẹ̀yin Àgbàlagbà—Ẹ Ní Iṣẹ́ Ribiribi Láti Ṣe (Sm 92:12-15): (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pé àkọlé rẹ̀ ní Ẹ̀yin Àgbàlagbà—Ẹ Ní Iṣẹ́ Ribiribi Láti Ṣe. (Lọ sí tv.pr418.com/yo, kó o sì wo abẹ́ WO FÍDÍÒ LÓRÍṢIRÍṢI > BÍBÉLÌ.) Lẹ́yìn náà, jẹ́ kí àwọn ará sọ àwọn ẹ̀kọ́ pàtàkì tí wọ́n rí kọ́. Gba àwọn àgbàlagbà níyànjú pé kí wọ́n máa ṣàjọpín ìrírí àti ọgbọ́n tí wọ́n ní pẹ̀lú àwọn ọ̀dọ́. Gba àwọn ọ̀dọ́ náà níyànjú pé kí wọ́n máa wá ìrànwọ́ lọ sọ́dọ̀ àwọn àgbàlagbà tí wọ́n bá fẹ́ ṣe àwọn ìpinnu pàtàkì.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 21 ìpínrọ̀ 13 sí 22, àtúnyẹ̀wò tó wà lójú ìwé 186

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 29 àti Àdúrà