Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Báwo ni Bíbélì ṣe lè ran àwọn tọkọtaya lọ́wọ́?

Bíbélì: Kol 3:12

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni Bíbélì ṣe lè ran àwọn òbí lọ́wọ́?

○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Báwo ni Bíbélì ṣe lè ran àwọn òbí lọ́wọ́?

Bíbélì: Kol 3:21

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni Bíbélì ṣe lè ran àwọn ọmọ lọ́wọ́?

○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ

Ìbéèrè: Báwo ni Bíbélì ṣe lè ran àwọn ọmọ lọ́wọ́?

Bíbélì: Owe 2:11

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí nìdí tí ìmọ̀ràn Bíbélì fi máa ń wúlò nígbà gbogbo?