August 27–September 2
Lúùkù 23-24
Orin 130 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ṣe Tán Láti Dárí Jini”: (10 min.)
Lk 23:34—Jésù dárí ji àwọn ọmọ ogun tó kàn án mọ́gi (cl 297 ¶16)
Lk 23:43—Jésù dárí ji ọ̀daràn kan (g 4/08 11 ¶5-6)
Lk 24:34—Jésù dárí ji Pétérù (cl 297-298 ¶17-18)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Lk 23:31—Kí ló ṣeé ṣe kí Jésù máa tọ́ka sí nínú ẹsẹ Bíbélì yìí? (“nígbà tí igi wà ní tútù, . . . nígbà tí ó bá rọ” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 23:31, nwtsty)
Lk 23:33—Àwọn nǹkan wo làwọn awalẹ̀pìtàn rí tó jẹ́ ká gbà pé ó ṣeé ṣe kí wọ́n máa fi ìṣó kan àwọn tí wọ́n bá fẹ́ pa mọ́gi? (“Ìṣó nínú Egungun Gìgísẹ̀” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Lk 23:33, àwòrán àti fídíò nwtsty)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lk 23:1-16
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún un ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó bá ipò rẹ̀ mu èyí tó wà nínú Àwọn Ohun Tá A Fi Ń Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́.
Ìpadàbẹ̀wò Kẹta: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwọ ni kó o yan ẹsẹ Bíbélì tó o máa lò, fi ọ̀kan nínú àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ lọ̀ ọ́.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 4 ¶3-4
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Jésù Kú fún Àwọn Arákùnrin Rẹ Náà”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Máa Sunwọ̀n Sí i Lójoojúmọ́!
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 12 ¶1-8
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 82 àti Àdúrà