ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI August 2019
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
Àwọn ìjíròrò tó dá lórí àwọn ìlérí tó dájú pé Ọlọ́run máa ṣe lọ́jọ́ iwájú.
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ọlọ́run Kò Fún Wa Ní Ẹ̀mí Ojo”
Tá a bá gbára lé agbára Ọlọ́run, ó máa fún wa nígboyà láti kojú àwọn ìṣòro wa.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Máa Kẹ́gbẹ́ Pẹ̀lú Àwọn Tó Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà
Àwọn tá à ń bá kẹ́gbẹ́ lè jẹ́ ká hùwà tó dáa tàbí èyí tí ò dáa.
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ẹ Yan Àwọn Alàgbà”
Àpẹẹrẹ tá a fi lélẹ̀ nínú Ìwé Mímọ́ ni wọ́n fi ń yan àwọn tó ń múpò iwájú nínú ìjọ Kristẹni lóde òní.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ẹ “Ní Ìtara fún Iṣẹ́ Rere”
Báwo làwọn ọ̀dọ́ ṣe lè jẹ́ kọ́wọ́ wọn tẹ àfojúsùn wọn láti di aṣáájú-ọ̀nà olùrànlọ́wọ́ tàbí aṣáájú-ọ̀nà déédéé?
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Nífẹ̀ẹ́ Òdodo, Kórìíra Ìwà Tí Kò Bófin Mu
Báwo la ṣe lè fi hàn pé a nífẹ̀ẹ́ òdodo, a sì kórìíra ìwà tí kò bófin mu?
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Sa Gbogbo Ipá Rẹ Kó O Lè Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run
Báwo la ṣe lè wọnú ìsinmi Ọlọ́run, kí la sì gbọ́dọ̀ ṣe láti dúró síbẹ̀?
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Àwọn Iṣẹ́ Rere Tá Ò Ní Gbàgbé
Kí làwọn nǹkan tá a retí lọ́wọ́ ẹni tó bá fẹ́ sìn ní Bẹ́tẹ́lì?