Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Ṣé ìgbà kan ń bọ̀ tí kò ní sẹ́ni tó máa ṣàìsàn mọ́?
Bíbélì: Ais 33:24
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni Ọlọ́run ṣe máa bá wa yanjú ebi tó ń han aráyé léèmọ̀?
○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Báwo ni Ọlọ́run ṣe máa bá wa yanjú ebi tó ń han aráyé léèmọ̀?
Bíbélì: Sm 72:16
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ìrètí wo ló wà fún àwọn èèyàn wa tó ti kú?
○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ
Ìbéèrè: Ìrètí wo ló wà fún àwọn èèyàn wa tó ti kú?
Bíbélì: Jo 5:28, 29
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí nìdí tó fi yẹ kó dá wa lójú pé àwọn ìlérí Ọlọ́run tó wà nínú Bíbélì máa nímùúṣẹ?