August 26–September 1
HÉBÉRÙ 4-6
Orin 5 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Sa Gbogbo Ipá Rẹ Kó O Lè Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run”: (10 min.)
Heb 4:1, 4—Mọ ọjọ́ ìsinmi Ọlọ́run (w11 7/15 24-25 ¶3-5)
Heb 4:6—Máa ṣègbọràn sí Jèhófà (w11 7/15 25 ¶6)
Heb 4:9-11—A ò gbọdọ̀ máa ṣe ohun tó wù wá nígbà gbogbo (w11 7/15 28 ¶16-17)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Heb 4:12—Kí ni “ọ̀rọ̀ Ọlọ́run” nínú àyíká ọ̀rọ̀ yìí? (w16.09 13)
Heb 6:17, 18—Kí ni “àwọn nǹkan méjì tí kò lè yí pa dà” tí ẹsẹ yìí mẹ́nu kàn? (it-1 1139 ¶2)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Heb 5:1-14 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Kejì—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 6)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 198-199 ¶7-8 (th ẹ̀kọ́ 12)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Àwọn Iṣẹ́ Rere Tá Ò Ní Gbàgbé”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Ohun Tó O Lè Ṣe Láti Ṣiṣẹ́ Sìn Ní Bẹ́tẹ́lì.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh 9 ¶16-18
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 12 àti Àdúrà