Orin 99 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ẹ Yan Àwọn Alàgbà”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Títù.]
Tit 1:5-9—Àwọn alábòójútó àyíká máa ń yan àwọn tó bá dójú ìlà ohun tí Ìwé Mímọ́ béèrè (w14 11/15 28-29)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Fílémónì.]
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Tit 1:12—Kí nìdí tá a fi lè sọ pé ẹsẹ Bíbélì yìí ò fọwọ́ sí kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà? (w89 5/15 31 ¶5)
Flm 15, 16—Kí nìdí tí Pọ́ọ̀lù ò fi sọ fún Fílémónì pé kó sọ Ónísímù dòmìnira? (w08 10/15 31 ¶4)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Tit 3:1-15 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 3)
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 12)
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Fún onílé ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 11)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ẹ ‘Ní Ìtara fún Iṣẹ́ Rere’”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò náà Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Ń Yin Jèhófà.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 9 ¶4-9
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 127 àti Àdúrà