December 12- 18
AÍSÁYÀ 6-10
Orin 116 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà Tó Ní Ìmúṣẹ ”: (10 min.)
Ais 9:1, 2
—Àsọtẹ́lẹ̀ ti wà nípa iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ̀ ní Gálílì (w11 8/15 ojú ìwé 10 ìpínrọ̀ 13; ip-1 ojú ìwé 124 sí 126 ìpínrọ̀ 13 sí 17) Ais 9:6
—Ó máa ní ọ̀pọ̀ ojúṣe lónírúurú láti bójú tó (w14 2/15 ojú ìwé 12 ìpínrọ̀ 18; w07 5/15 ojú ìwé 6) Ais 9:7
—Ìṣàkóso rẹ̀ máa mú àlááfíà àti ìdájọ́ òdodo wá fún aráyé (ip-1 ojú ìwé 132 ìpínrọ̀ 28 àti 29)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Ais 7:3, 4
—Kí nìdí tí Jèhófà fi dáàbò bo Áhásì Ọba tó jẹ́ ẹni burúkú? (w06 12/1 ojú ìwé 9 ìpínrọ̀ 4) Ais 8:1-4
—Báwo ni àsọtẹ́lẹ̀ yìí ṣe ní ìmúṣẹ? (it-1-E ojú ìwé 1219; ip-1 ojú ìwé 111 àti 112 ìpínrọ̀ 23 àti 24) Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?
Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 7:1-17
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Àwòrán iwájú ìwé ìròyìn g16.6 tó wà lójú ìwé 2
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g16.6
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv ojú ìwé 34 ìpínrọ̀ 18
—Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Orin 10
“Èmi Nìyí! Rán Mi!” (Ais 6:8): (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní A Kó Lọ Síbi Tí Wọ́n Ti Nílò Oníwàásù Púpọ̀ Sí I] .
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 5 ìpínrọ̀ 10 sí 17, àpótí “Ọkàn Ti Wá Balẹ̀ Dáadáa Wàyí”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 150 àti Àdúrà
Ìránnilétí: Jẹ́ kí àwọn ará kọ́kọ́ gbọ́ orin tuntun yìí lẹ́ẹ̀kan, lẹ́yìn náà, kí ẹ kọ ọ́.