December 19- 25
AÍSÁYÀ 11-16
Orin 143 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ilẹ̀ Ayé Yóò Kún fún Ìmọ̀ Jèhófà”: (10 min.)
Ais 11:3-5
—Òdodo yóò gbilẹ̀ títí láé (ip-1 ojú ìwé 160 àti 161 ìpínrọ̀ 9 sí 11) Ais 11:6-8
—Àlááfíà máa wà láàárín àwọn èèyàn àti ẹranko (w12 9/15 ojú ìwé 9 àti 10 ìpínrọ̀ 8 àti 9) Ais 11:9
—Gbogbo èèyàn máa kẹ́kọ̀ọ́ nípa Jèhófà (w16.06 ojú ìwé 8 ìpínrọ̀ 9; w13 6/1 ojú ìwé 7)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Ais 11:1, 10
—Báwo ni Jésù Kristi ṣe lè jẹ́ “gbòǹgbò Jésè” síbẹ̀ kó tún jẹ́ ẹ̀ka igi kan tó yọ láti “ara kùkùté Jésè”? (w06 12/1 ojú ìwé 9 ìpínrọ̀ 6) Ais 13:17
—Ọ̀nà wo làwọn ará Mídíà kò fi ka fàdákà sí ohunkóhun tí Wọn kò sì ní inú dídùn sí wúrà? (w06 12/1 ojú ìwé 10 ìpínrọ̀ 10) Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?
Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 13:17–14:8
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Job 34:10
—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni. Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Onw 8:9; 1Jo 5:19
—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv ojú ìwé 54 ìpínrọ̀ 9
—Fi béèyàn ṣe lè dé ọkàn akẹ́kọ̀ọ́ hàn.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Orin 24
“Ẹ̀kọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Borí Ìwà Ẹ̀tanú”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Johny àti Gideon: Ọ̀tá Ni Wọ́n Tẹ́lẹ̀, Wọ́n Ti Di Arákùnrin Báyìí.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 5 ìpínrọ̀ 18 sí 25, àpótí “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 151 àti Àdúrà
Ìránnilétí: Jẹ́ kí àwọn ará kọ́kọ́ gbọ́ orin tuntun yìí lẹ́ẹ̀kan, lẹ́yìn náà, kí ẹ kọ ọ́.