Wọ́n ń kọrin nígbà ìjọsìn ìdílé lórílẹ̀-èdè South Africa

ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI December 2018

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ìjíròrò tó dá lórí ìdí tí Ọlọ́run fi dá wa sáyé àti ohun tó fẹ́ ṣe fún wa lọ́jọ́ iwájú.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ẹni Tó Ń Ṣe Inúnibíni Di Ẹni Tó Ń Fìtara Wàásù

Tó o bá ń kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì àmọ́ tó ò tí ì ṣèrìbọmi, ṣé wàá ṣe bíi ti Sọ́ọ̀lù, ṣé wàá ṣiṣẹ́ lórí ohun tó ò ń kọ́?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Bánábà àti Pọ́ọ̀lù Sọ Àwọn Èèyàn Tó Wà Láwọn Ọ̀nà Jíjìn Di Ọmọlẹ́yìn

Àwọn èèyàn ta ko Bánábà àti Pọ́ọ̀lù, síbẹ̀ àwọn méjèèjì ṣiṣẹ́ kára káwọn ọlọ́kàn tútù lè di Kristẹni.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I​​—Ran Àwọn Tó Ní “Ìtẹ̀sí-Ọkàn Títọ́” Lọ́wọ́ Láti Di Ọmọlẹ́yìn

Báwo la ṣe lè bá Jèhófà ṣiṣẹ́ pọ̀ tá a bá ń wá àwọn tó máa di ọmọlẹ́yìn?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Wọ́n Fìmọ̀ Ṣọ̀kan Láti Ṣe Ìpinnu Tó Dá Lórí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

Ẹ̀kọ́ wo la rí kọ́ nínú bí wọ́n ṣe yanjú ìṣòro náà?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Fi Orin Yin Jèhófà

Tá a bá ń kọ orin Ìjọba Ọlọ́run, àǹfààní wo ló máa ṣe fún wa?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Fara Wé Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù Bó O Ṣe Ń Wàásù Tó O sì Ń Kọ́ni

Báwo la ṣe lè fara wé àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Ẹ Kíyè Sí Ara Yín àti Gbogbo Agbo”

Àwọn alàgbà máa ń bọ́ àwọn àgùntàn Ọlọ́run, wọ́n máa ń dáàbò bò wọ́n, wọ́n sì máa ń tọ́jú wọn, torí wọ́n mọ̀ pé ẹ̀jẹ̀ iyebíye Kristi ni Ọlọ́run fi ra ẹnì kọ̀ọ̀kan wọn.