Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Kí nìdí tí Ọlọ́run fi dá wa sáyé?

Bíbélì: Jẹ 1:27, 28

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ló jẹ́ ká gbà pé Ọlọ́run máa ṣe ohun tó ní lọ́kàn?

○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Kí ló jẹ́ ká gbà pé Ọlọ́run máa ṣe ohun tó ní lọ́kàn?

Bíbélì: Joṣ 21:45

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ni Ọlọ́run sọ pé òun máa ṣe lọ́jọ́ iwájú?

○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ

Ìbéèrè: Kí ni Ọlọ́run sọ pé òun máa ṣe lọ́jọ́ iwájú?

Bíbélì: Iṣi 21:4

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ló yẹ ká ṣe ká lè gbádùn àwọn ìbùkún tí Ọlọ́run ṣèlérí?