December 10-16
ÌṢE 12-14
Orin 60 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Bánábà àti Pọ́ọ̀lù Sọ Àwọn Èèyàn Tó Wà Láwọn Ọ̀nà Jíjìn Di Ọmọlẹ́yìn”: (10 min.)
Iṣe 13:2, 3—Jèhófà yan Bánábà àti Sọ́ọ̀lù fún iṣẹ́ pàtàkì kan (bt 86 ¶4)
Iṣe 13:12, 48; 14:1—Iṣẹ́ àṣekára tí wọ́n ṣe mú èso jáde (bt 95 ¶5)
Iṣe 14:21, 22—Bánábà àti Sọ́ọ̀lù fún àwọn ọmọlẹ́yìn tuntun níṣìírí (w14 9/15 13 ¶4-5)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Iṣe 12:21-23—Kí la rí kọ́ látinú ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Hẹ́rọ́dù? (w08 5/15 32 ¶7)
Iṣe 13:9—Kí nìdí tí wọ́n tún ń pe Sọ́ọ̀lù ní Pọ́ọ̀lù? (“Sọ́ọ̀lù, ẹni tí ó tún ń jẹ́ Pọ́ọ̀lù” àti “Pọ́ọ̀lù” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 13:9, nwtsty)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣe 12:1-17
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ.
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Àsọyé: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bt 79 ¶8-9—Àkòrí: Máa Gbàdúrà Fún Àwọn Tá A Jọ Jẹ́ Onígbàgbọ́.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Ran Àwọn Tó Ní ‘Ìtẹ̀sí-Ọkàn Títọ́’ Lọ́wọ́ Láti Di Ọmọlẹ́yìn”: (15 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò náà Jèhófà Ọlọ́run Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lv orí 17 ¶1-10
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 55 àti Àdúrà