Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

December 24-​30

ÌṢE 17-18

December 24-​30
  • Orin 78 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Fara Wé Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù Bó O Ṣe Ń Wàásù Tó O sì Ń Kọ́ni”: (10 min.)

    • Iṣe 17:2, 3​—Pọ́ọ̀lù máa ń báni fèrò wérò látinú Ìwé Mímọ́, ó sì máa ń tọ́ka nígbà tó bá ń kọ́ni (“fèrò-wérò” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 17:2; fi ẹ̀rí ìdánilójú hàn nípasẹ̀ àwọn ìtọ́ka” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 17:3, nwtsty)

    • Iṣe 17:17​—Gbogbo ibi tí Pọ́ọ̀lù bá ti rí àwọn èèyàn ló ti máa ń wàásù (“ní ibi ọjà” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 17:17, nwtsty)

    • Iṣe 17:22, 23​—Pọ́ọ̀lù jẹ́ ẹni tó ní àkíyèsí, ibi tí ọ̀rọ̀ òun àtàwọn tó ń wàásù fún ti bara mu ló sì ti máa ń bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ rẹ̀ (“Sí Ọlọ́run Àìmọ̀” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 17:22, 23, nwtsty)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Iṣe 18:18​—Kí la lè sọ nípa ẹ̀jẹ́ tí Pọ́ọ̀lù jẹ́? (w08 5/15 32 ¶5)

    • Iṣe 18:21​—Báwo la ṣe lè fara wé Pọ́ọ̀lù bá a ṣe ń lé àwọn àfojúsùn nínú ìjọsìn Jèhófà? (“bí Jèhófà bá fẹ́” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Iṣe 18:21, nwtsty)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Iṣe 17:1-15

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI